BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipese Aabo fun ilu
Adájọ́ kẹ́de ọjọ́ ìdájọ́ fún Abdulraman Bello àtàwọn míràn tí wọ́n fi ẹ̀sùn ṣíṣekúpa akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin kàn ní Ilorin
2 Agẹmo 2025
Ta làwọn agbébọn tó ṣekúpa èèyàn tó lé ní mẹ́wàá l'Anambra
2 Agẹmo 2025
Àwọn èèyàn ìlú Ido-Ayegunle àti Esa Oke kọlu ara wọn lórí àlà ilẹ̀ ní Osun, ẹ̀mí bọ́, dúkìá ṣòfò, ìlú dahoro
2 Agẹmo 2025
Ẹ wo bí ìgbẹ́jọ́ àwọn afurasí tó ṣagbátẹrù CBEX ṣe lọ nílé ẹ̀jọ́ lónìí
1 Agẹmo 2025
Àwọn ọ̀dọ́ ìlú Lafiagi ṣe ìfẹ̀hónúhàn, jo Iléeṣẹ́ NDLEA, ba ààfin ọba jẹ́ nítorí ìjínigbé tó di lemọ́
1 Agẹmo 2025
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá fẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní mú aráàlú lórí ìwọ̀kuwọ̀ aṣọ, kí ni òfin sọ lórí èyí?
30 Òkùdu 2025
Lẹ́yìn táwọn agbébọn pa bàbá àti ọmọ tán ní ìjọba ìbílẹ̀ Patigi, wọ́n tún ń bèèrè fún ₦200m, tàbí kí wọ́n padà wá
29 Òkùdu 2025
Kí ló mú eégún mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ dèrò ẹ̀wọ̀n láìrò tẹ́lẹ̀? Àlàyé rèé
29 Òkùdu 2025
Olóyè dèrò àhámọ́ ọlọ́pàá l'Ondo lórí ẹ̀sùn pé ó há ọmọdébìnrin mọ́lé, hu ìwà kòtọ́ pẹ̀lú rẹ
27 Òkùdu 2025
Ilé ẹjọ́ dájọ́ ikú fún akọrin ẹ̀mí, Timileyin Ajayi tó pa ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀, Salome Adaidu
26 Òkùdu 2025
Akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Leadcity méjì, ìyàwó ilé àti dẹ́rẹ́bà ọkọ̀ Micra, kú nínú ìjàm̀bá ọkọ̀ n'Ibadan
24 Òkùdu 2025
'Obìnrin ló wa ọkọ̀ 'one chance' tí mo wọ̀, wọ́n lù mí bíi kí n kú, wọ́n tún fi aboniki sí mi lójú'
23 Òkùdu 2025
Awọn afurasí agbésùnmọ̀mí pa èèyàn mẹ́wàá ní Borno
22 Òkùdu 2025
'Gbogbo ìlú wa ló ti dahoro nítorí ìkọlù àwọn agbébọn'
21 Òkùdu 2025
Bí a ṣe mú afurasí ògbóǹtarìgì olórí agbénipa àti adigunjalè tó ń pàwọn èèyàn lẹ́kún ní ìpínlẹ̀ Eko rèé - Ọlọ́pàá
21 Òkùdu 2025
Ọwọ́ ẹ̀ṣọ́ Fijilanté àti ọlọ́pàá ba afurasí ajínigbé méjì pẹ̀lú àjà ilẹ̀ nínú ilé àkọ́patì kan, jìnnì jìnnì ba aráàlú
21 Òkùdu 2025
"Nnamdi Kanu ní kí a sin òkú adarí Ipob pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún méjì orí èèyan, a ti pa ọgbọ̀n èèyàn kí ọwọ́ ọlọ́pàá tó tẹ̀ wá"
20 Òkùdu 2025
"Ó dàbí pé ìjọba ti gbàgbé wa ni àwọn agbébọn ṣe ń kọlù wá lọ́pọ̀ ìgbá, ẹ̀mí mọ́kàǹlá ló bọ́ lọ́tẹ̀ yìí"
20 Òkùdu 2025
Ṣàdéédé ni ọkùnrin kan bọ sílẹ̀ lórí ọkàdá, yínbon lú oní POS àti ọmọ rẹ̀ ní ìlú Ibadan- Óṣojúmikòró
19 Òkùdu 2025
Kí ni Stun Gun àti pé kí ni òfin sọ nípa lílò rẹ̀ ní Naijiria?
18 Òkùdu 2025
0:59
Orin,
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
, Duration 0,59
18 Òkùdu 2025
Ọ̀pọ̀ egúngún yabo mọ́sálásí, lu ìyàwó Imam agba, ọmọ rẹ, ọ̀rọ̀ di bóò lọ yàgò l'Ondo
18 Òkùdu 2025
Pásítọ̀ Adefarasin fara kalẹ̀ fún ìwádìí lórí ẹ̀sùn pé ó yọ nnkan tó jọ ìbọn sí èèyàn kan
17 Òkùdu 2025
0:57
Orin,
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
, Duration 0,57
17 Òkùdu 2025
Ìṣájú
Page
17
nínú
40
1
14
15
16
17
18
19
20
40
Tókàn