BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Igbeyawo
Òfin tí yóò fààyè gba obìnrin láti ní ọkọ méjì ń bọ̀ lọ́nà
16 Èbibi 2021
Obìnrin tó n wá orí adé láti fi ṣe ọkọ pàdánù ₦51m sọ́wọ́ gbájúẹ̀ l'Eko
1 Èbibi 2021
Olórùka ti gba òrùka, n kò sí lórí àtẹ mọ́, ẹ má sanwó láti fẹ́ mi - Oluwo figbeta
29 Ìgbé 2021
Mo nífẹ̀ẹ́ ọkọ mi si lẹ́yìn ikú rẹ̀ ju ojú ayé rẹ̀ lọ - Florence Ajimobi
29 Ìgbé 2021
Nǹkán yan, wọ́n ń ṣe ìkówójọ fún Olorì Damilola láti fi gba ilé l‘Eko
28 Ìgbé 2021
Mo fẹ́ ìyàwó méjì lọ́jọ́ kan ṣoṣo láti ṣe ju ohun tí bàbá mi gbé ṣe - Uloho Othuko
24 Ìgbé 2021
‘Jí foonu ọkọ rẹ̀ wò, kóo fi ẹ̀wọ̀n jura’
24 Ìgbé 2021
Wo àwọn àmì mẹ́jọ ti o lè fi mọ̀ pé ọkọ tàbí aya rẹ ti ń ṣe ìta
18 Ìgbé 2021
Ìgbeyàwó mú kí àpọ́nlé tó pọ̀ wà fún mi ju ti tẹ́lẹ̀ lọ - Tayo Sobola
17 Ìgbé 2021
Ojú wa rí, a ṣe IVF, oyún ìbeji bàjẹ́ kí á tó di ọlọ́mọ láyé - Adesua àti Banky W
6 Ìgbé 2021
Òjò ìfẹ́ rọ̀, Miss Pepeiye ṣe ìyàwó pẹ̀lú agbábọ́ọ̀lù Super Eagles, Peter Olayinka
28 Ẹrẹ̀nà 2021
6:55
Fídíò,
'Oríi bẹ́ẹ̀dì nìkan ni ìjà wà lè ti bẹ̀rẹ̀, orí bẹ́ẹ̀dì náà ló gbúdọ̀ parí sí, ko kan mọ̀lẹ́bí'
, Duration 6,55
27 Ẹrẹ̀nà 2021
Ṣé òótọ́ ni pé Yusuf Buhari ń múra láti gbé Ọmọọbabìnrin Zahra Bayero níyàwó?
25 Ẹrẹ̀nà 2021
Ìdí rèé ti mo fi gbé àfẹ́sọ́nà ẹ̀gbọ́n mi níyàwó lẹ́yìn ikú rẹ̀
24 Ẹrẹ̀nà 2021
Ọmọ ọdún mẹ́rìnlá làwọn ọkùnrin ti ń fipá bá mi lòpọ̀ nígbà márùn-ún - Iyabo Ojo
14 Ẹrẹ̀nà 2021
Kí nìdí tí gbajúgbajà òṣèré Sotayo Gaga ṣègbéyàwó bóńkẹ́lẹ́?
7 Ẹrẹ̀nà 2021
Èsì tí Daddy Freeze fọ̀ lórí owó N5m tí ilé ẹjọ́ ní kó san fún ọkọ obìnrin tó yàn l'álè rèé
7 Ẹrẹ̀nà 2021
Ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọlọ́mọ mẹ́jọ ká nítorí pé ọkọ rí àwọn òbí ìyàwó fín
6 Ẹrẹ̀nà 2021
Wòlíì Kasali gba Bunmi ìyàwó rẹ̀ àkọ́fẹ́ padà, ìjà parí!
5 Ẹrẹ̀nà 2021
Ẹ tú ìgbéyàwó wa ká, níṣe n'ìyàwó mi máa ń gbá mi létí- ọkùnrin kan sọ fún iléẹjọ́
1 Ẹrẹ̀nà 2021
Fáàbàdà! Ìjọba mi kọ́ ní yóò buwọ́lu ìgbéyàwó akọ sákọ àti abo sábo- Ààrẹ Ghana yarí
28 Èrèlè 2021
7:27
Fídíò,
Wo bí àrokò ṣe ń jẹ́ bí idán láyé àtijọ́ nílẹ̀ Yorùbá?
, Duration 7,27
23 Èrèlè 2021
Ọkùnrin kan gún olólùfẹ́ rẹ̀ lọ́bẹ lórí N85,000 lẹ́yìn tó kọ̀ láti ṣèyàwó pẹ̀lú rẹ̀
20 Èrèlè 2021
Iléẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọdún méje ká lórí ẹ̀sùn àìjọgbé papọ̀
6 Èrèlè 2021
Ìṣájú
Page
16
nínú
21
1
13
14
15
16
17
18
19
20
21
Tókàn