BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Oyo
Ẹgbẹ́ òṣèlú APC Oyo sún ètò ìdìbò abẹ́nú sí òní, ìdí rèé
27 Èbibi 2022
Seyi Makinde ni PDP gbade fún láti díje dupò gómìnà Oyo lẹ́ẹ̀kán síi nínú ìdìbò abẹnu yìí
25 Èbibi 2022
Lẹ́yìn idojúkọ ASUU, LAUTECH kéde pé kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọlé wa parí sáà ètò ẹ̀kọ́ tó bẹ̀rẹ̀ tẹ́lẹ̀
25 Èbibi 2022
Gbajúmọ̀ Olórin Banky W ti rí tíkẹ̀ẹ̀tì ẹgbẹ́ òṣèlú PDP gbà láti díje dupò aṣòfin
24 Èbibi 2022
2:30
Fídíò,
Aṣọ ẹsikí tí mo wọ̀ ló sọ mi di ọlọ́wọ́ kan nígbà tí mo lọ lo ọludé- Toheeb
, Duration 2,30
24 Èbibi 2022
Àwọn Jàǹdùkú kọlù alága àjọ tó ń ṣètò eré ìdárayá ní ìpínlẹ̀ Oyo
23 Èbibi 2022
Ìwà aṣemáṣe gbaṣẹ́ lọ́wọ́ dókítà àti nọ́ọ̀sì ní ìpínlẹ̀ Oyo
22 Èbibi 2022
9:01
Fídíò,
Ọmọ ìyá méjì ni a pàdánù láàrin ọjọ́ mẹ́ta, ọ̀rọ̀ Dayo nílò ìwádìí, ẹ dẹ́kun isọkúsọ- ẹbí akẹ́kọ̀ọ́ Poly
, Duration 9,01
22 Èbibi 2022
Lẹ́yìn wákàtí díẹ̀ tí wọ́n sin òkú n'Ibadan, àwọn afurasí olóogùn owó gé orí rẹ̀ lọ
20 Èbibi 2022
Mo ti ṣetán láti gba ìjọba lọ́wọ́ Makinde lọ́dún 2023 - Adebayo Adelabu
20 Èbibi 2022
7:06
Fídíò,
'Ọ̀pọ̀ ìgbà l'èmí gan fẹ́ du àwọn ipò òṣèlú kan lọ́dún 2015, 2019, àmọ́ mo tẹ 'slow' torí bàbà mi, Akala náà ń jáde'
, Duration 7,06
17 Èbibi 2022
Wo bí wọ́n ṣe ń ṣètò ìṣàkóso ní Alaàfin ìlú Oyo bóyá aáàfin wà láyé tàbí o ti papòdà
14 Èbibi 2022
7:33
Fídíò,
Ìjòba Oyo ló bẹ̀ mí láti fááyé gba fún Oba Lamidi Adeyemi ní 1971- Omooba Tijani Olawoyin Atiba
, Duration 7,33
13 Èbibi 2022
Ṣé lóòtọ́ ní Makinde gbà tíkẹ̀ẹ̀tì Sẹ́nétọ̀ lọ́wọ́ Kola Balogun fún Joseph Tegbe?
11 Èbibi 2022
Wo àwọn obìnrin mẹ́wàá tí ipa wọn kò ṣe fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn ní ààfin Oyo
11 Èbibi 2022
Ìjọba Oyo dá ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ ìtàn "History" padà sí ilé ẹ̀kọ́ alákọ̀bẹ̀rẹ̀
10 Èbibi 2022
4:15
Fídíò,
Wọ́n 'Poison' Aláàfin Oyo ni, ikú Bàbá dùn mi púpọ̀- Sat Guru Maharaj-ji
, Duration 4,15
10 Èbibi 2022
Aláàrun ọpọlọ kọlu Ààfin Soun Ogbomoso, ó fi ẹ̀ṣẹ́ yọ eyín Olóyè
6 Èbibi 2022
Àwọn afurasí apààyàn pa 'Atiku' ní Ibarapa!
3 Èbibi 2022
6:50
Fídíò,
Babalawo, Ọ̀pẹ̀lẹ̀ ni wọ́n fi ń yan Ọba fún wa, kí ló dé tẹ́ẹ fẹ́ wo owó yan Soun fún wa? - Ọmọ ìdílé òyè l'Ogbomoso
, Duration 6,50
3 Èbibi 2022
4:36
Fídíò,
Èmi nìkan ni ikú Alaafin dùn jù ní gbogbo ayé yìí torí èmi nìkàn ṣoṣo ni mo mọ̀ ǹkan ... - Baba Kekere
, Duration 4,36
2 Èbibi 2022
Alaafin Oyo tuntun yóò gorí ìtẹ́ láìpẹ́ - Makinde
1 Èbibi 2022
Ǹkan tí èmi àti Alaafin jọ ṣe sílẹ́ lórí àṣà Yorùbá kìí ṣe kèrémí - Òyìnbó òṣìṣẹ́
1 Èbibi 2022
Òní ni ọjọ́ mẹ́jọ ìpapòdà Oba Lamidi Adeyemi ni ìlú Oyo
30 Ìgbé 2022
Ìṣájú
Page
31
nínú
40
1
28
29
30
31
32
33
34
40
Tókàn