BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Eto Irinna
Kí ló fa rògbòdìyàn tó gbòde ní Ajah, tí ẹ̀mí méjì fi bọ́, tí ọ̀pọ̀ dúkìá sì bájẹ́?
16 Ẹrẹ̀nà 2022
Ṣé lóòtọ́ọ́ ní àwọn awakọ̀ èrò fẹ́ ṣe ìwọ́de lónìí l‘Eko torí yíyọ MC Oluomo nípò?
16 Ẹrẹ̀nà 2022
"Ọ̀pọ̀ èrò ló ń sá padà láti wọnú ọkọ̀ mi torí ń kò ní ẹsẹ̀ méjééjì"
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Ìjàmbá ọkọ̀ tún gbẹ̀mí ènìyàn mẹ́tàlá ní òpópónà márosẹ̀ Ilorin sí Ogbomoso
12 Ẹrẹ̀nà 2022
Lẹ́yìn tí wọ́n gba ipò alága NURTW lọ́wọ́ rẹ̀, MC Oluomo yapá kúró ní NURTW
10 Ẹrẹ̀nà 2022
5:35
Fídíò,
'Hááà! Bamise mà jìyà o, ó l'óun á mu mi kúrò nílé àyágbé àmọ́ ó wá di ẹni tí wọ́n yọ pátá lára rẹ̀'
, Duration 5,35
9 Ẹrẹ̀nà 2022
Wọ́n gbé ìbọn sí mi léti lásìkò tí mò ń wa ọkọ̀ BRT tí Bamise ti dàwátì, mi ò mọ bó ṣe ń ṣe mí rárá- Dẹ́rẹ́bà BRT
8 Ẹrẹ̀nà 2022
Ọkọ̀ tó rìn gba "one way" gbá ọmọ ìyá mẹ́rin lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo l'Eko, ọ̀kan kú
7 Ẹrẹ̀nà 2022
Aláboyún àti èèyàn mẹ́jọ míì jóná kọjá mímọ̀ nínú ìjàmbá ọkọ̀ n'Ilorin
20 Èrèlè 2022
Awakọ̀ dáná sun ara rẹ̀ lórí bí àwọn 'task force' ṣe mu l'Eko
16 Èrèlè 2022
Ìjà abẹ́nú bẹ̀rẹ̀ lẹ́gbẹ́ NURTW l‘Eko, nǹkan kò fara rọ
11 Èrèlè 2022
NNPC di ẹ̀bí ayédèrú epo tó wọ Nàìjíríà ru iléeṣẹ́ mẹ́rin
10 Èrèlè 2022
Sanwo-Olu kède iye tí àwọn aráàlú yóò máa wọ ọkọ̀ ojú irin ayára bí àṣá tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ́ rà
28 Sẹ́rẹ́ 2022
Ìjọba Eko gbẹ́sẹ̀lé NURTW ní Lagos Island, ọlọ́pàá mú àwọn méjì míì lórí ìjà ìgboro Idumota
25 Sẹ́rẹ́ 2022
Ọlọ́pàá Oyo bẹ̀rẹ̀ kán lu ìgbó láti wá àwọn ajínigbé lópópónà Lagos-Ibadan Expressway
20 Sẹ́rẹ́ 2022
Mu pàrágá wakọ̀ l'Oyo, kóo kó sí gbaga ìjọba
22 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Abiyamọ, ọmọ rẹ̀ àti èèyàn kan bá ìbúgbàmù ọkọ́ aképo lọ́ ní Lafenwa
28 Bélú 2021
Ọdún tó ń bọ̀ ni okọ̀ òfúrufú ‘Air Nigeria’ yóò gbérasọ
24 Bélú 2021
Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko rún alùpùpù 482 tí wọ́n gbà lọ́wọ́ àwọn ọlọ́kadà jégé-jégé
20 Bélú 2021
Wo ìdí tí àwọn òṣìṣẹ́ ọ̀kọ̀ Reluwé ṣe da iṣẹ́ sílẹ̀ jákèjádò Nàìjíríà
18 Bélú 2021
Wo ìdí tí ìjọba Naijiria ṣe fẹ́ ẹ́ ta iléèṣẹ́ ọkọ̀ reluwé fún aládàáni
14 Bélú 2021
Ọ̀kadà tó n lo iná ẹ̀lẹ́tíríìkì wọ̀lú! Ó le ṣe iṣẹ́ wákàtí mẹ́wàá láì dáwọ́ dúró
9 Bélú 2021
Ìyà tó ń jẹ Ife lórí òpópónà tó bàjẹ́ kò tọ́, Buhari, Oyetola, ẹ wá nǹkan ṣe sí - Ooni
1 Bélú 2021
Omi ìdọ̀tí atí ''biscuit'' la jẹ fún ọjọ́ méje - Àwọn àgùnbánírọ̀ sọ ìrírí wọ́n lọ́wọ́ ajínígbé
30 Ọ̀wàrà 2021
Ìṣájú
Page
12
nínú
17
1
9
10
11
12
13
14
15
16
17
Tókàn