Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Mi o ni erongba lati di gomina ipinlẹ Osun lati ibẹrẹ, amọ Ọlọrun ti kadara mi pe mo maa de ipo naa

Oludije sipo gomina ninu ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Osun, Bola Oyebamiji, ti ọpọ mọ si AMBỌ lo sọ bẹẹ fun BBC

O ni iṣẹ agbẹ loun yoo kọkọ gbajumọ gẹgẹ bii gomina

___________________________________________________

Hmmmmm... Agbọn n sẹ, ikamudu n sẹ, oju oloko ree to wu kọndu-kọndu

Ẹgbẹ oṣelu APC ati Accord ipinlẹ Osun ti tako ara wọn

Lẹyin rogbodiyan to gbẹmi eeyan meji, ti ọpọ tun ti farapa niluu Osogbo

APC ni awọn janduku ẹgbẹ Accord lo kọju ija si awọn ọmọ ẹgbẹ APC

Nigba ti Accord fesi pe awọn janduku APC gan lo n da igboro ru

Ẹkunrẹrẹ wa loju opo wa

___________________________________________________

Ile ẹjọ ti paṣẹ ki ijọba gbẹsẹle dukia olowo iyebiye to jẹ ti gbajugbaja olokoowo nni, Arabinrin Aisha Achimugu

Lara dukia naa ni ẹṣọ ara ti iye rẹ le ni biliọnu mẹrin naira

Ti o ba fẹ mọ ẹkunrẹrẹ